Jẹnẹsisi 1:21 BM

21 Ó dá àwọn ẹranko ńláńlá inú omi ati oríṣìíríṣìí ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi, ati oríṣìíríṣìí ẹyẹ. Ọlọrun wò wọ́n, ó sì rí i pé wọ́n dára.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:21 ni o tọ