31 Ọlọrun wo gbogbo ohun tí ó dá, ó sì rí i pé wọ́n dára. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ kẹfa.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1
Wo Jẹnẹsisi 1:31 ni o tọ