Jẹnẹsisi 10:20 BM

20 Àwọn ọmọ Hamu nìwọ̀nyí ní ìdílé ìdílé wọn, olukuluku ní agbègbè tirẹ̀, oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè ni wọ́n, wọ́n sì ń sọ oríṣìíríṣìí èdè.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 10

Wo Jẹnẹsisi 10:20 ni o tọ