Jẹnẹsisi 11:10 BM

10 Àkọsílẹ̀ ìran Ṣemu nìyí: ọdún keji lẹ́yìn tí ìkún omi ṣẹlẹ̀, tí Ṣemu di ẹni ọgọrun-un (100) ọdún ni ó bí Apakiṣadi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11

Wo Jẹnẹsisi 11:10 ni o tọ