27 Àkọsílẹ̀ ìran Tẹra nìyí: Tẹra ni baba Abramu, Nahori ati Harani. Harani sì ni baba Lọti.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11
Wo Jẹnẹsisi 11:27 ni o tọ