8 Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe fọ́n wọn káàkiri sí gbogbo orílẹ̀ ayé, wọ́n pa ìlú náà tí wọn ń tẹ̀dó tì.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 11
Wo Jẹnẹsisi 11:8 ni o tọ