Jẹnẹsisi 12:1 BM

1 Ní ọjọ́ kan, Ọlọrun sọ fún Abramu pé, “Jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ, láàrin àwọn ìbátan rẹ, ati kúrò ní ilé baba rẹ lọ sí ilẹ̀ kan tí n óo fi hàn ọ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12

Wo Jẹnẹsisi 12:1 ni o tọ