Jẹnẹsisi 12:19 BM

19 Èéṣe tí o fi sọ pé tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni yín, tí o jẹ́ kí n fi ṣe aya? Iyawo rẹ nìyí, gba nǹkan rẹ, kí o sì máa lọ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12

Wo Jẹnẹsisi 12:19 ni o tọ