6 Abramu la ilẹ̀ náà kọjá lọ sí ibi igi Oaku ti More, ní Ṣekemu. Àwọn ará Kenaani ni wọ́n ń gbé ilẹ̀ náà nígbà náà.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 12
Wo Jẹnẹsisi 12:6 ni o tọ