1 Bẹ́ẹ̀ ni Abramu ṣe jáde kúrò ní Ijipti, ó pada lọ sí Nẹgẹbu pẹlu aya rẹ̀, ati Lọti ati ohun gbogbo tí ó ní.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13
Wo Jẹnẹsisi 13:1 ni o tọ