Jẹnẹsisi 13:16 BM

16 N óo mú kí àwọn ọmọ rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tí yóo fi jẹ́ pé, àfi ẹni tí ó bá lè ka iye erùpẹ̀ ilẹ̀ ni yóo lè kà wọ́n.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13

Wo Jẹnẹsisi 13:16 ni o tọ