Jẹnẹsisi 13:18 BM

18 Nítorí náà, Abramu kó àgọ́ rẹ̀ wá sí ibi igi Oaku ti Mamure, tí ó wà ní Heburoni, níbẹ̀ ni ó ti tẹ́ pẹpẹ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13

Wo Jẹnẹsisi 13:18 ni o tọ