12 Ọwọ́ wọn tẹ Lọti, ọmọ arakunrin Abramu tí ń gbé ní Sodomu, wọ́n mú un lẹ́rú, wọ́n sì kó gbogbo ẹran ọ̀sìn ati gbogbo ohun ìní rẹ̀ lọ.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14
Wo Jẹnẹsisi 14:12 ni o tọ