Jẹnẹsisi 14:16 BM

16 Abramu gba gbogbo ìkógun tí wọ́n kó pada, ó gba Lọti, ìbátan rẹ̀ pẹlu ati gbogbo ohun ìní rẹ̀, ati àwọn obinrin ati ọ̀pọ̀ àwọn eniyan mìíràn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14

Wo Jẹnẹsisi 14:16 ni o tọ