Jẹnẹsisi 14:4 BM

4 Fún ọdún mejila gbáko ni àwọn ọba maraarun yìí fi sin Kedorilaomeri, ṣugbọn ní ọdún kẹtala, wọ́n dìtẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14

Wo Jẹnẹsisi 14:4 ni o tọ