Jẹnẹsisi 14:7 BM

7 Nígbà náà ni wọ́n tó yipada tí wọ́n sì wá sí Enmiṣipati (tí ó tún ń jẹ́ Kadeṣi), wọ́n sì ṣẹgun gbogbo ilẹ̀ àwọn ará Amaleki ati ti àwọn ará Amori tí ń gbé Hasasoni Tamari.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14

Wo Jẹnẹsisi 14:7 ni o tọ