9 Wọ́n gbógun ti Kedorilaomeri, ọba Elamu, Tidali, ọba Goiimu, Amrafeli, ọba Babiloni ati Arioku, ọba Elasari. Ọba mẹrin dojú kọ ọba marun-un.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14
Wo Jẹnẹsisi 14:9 ni o tọ