Jẹnẹsisi 15:11 BM

11 Nígbà tí àwọn ẹyẹ tí wọ́n máa ń jẹ òkú ẹran rábàbà wá sí ibi tí Abramu to àwọn ẹran náà sí, ó lé wọn.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15

Wo Jẹnẹsisi 15:11 ni o tọ