Jẹnẹsisi 15:14 BM

14 Ṣugbọn n óo mú ìdájọ́ wá sórí orílẹ̀-èdè náà tí wọn yóo sìn. Àṣẹ̀yìnwá, àṣẹ̀yìnbọ̀, wọn yóo jáde kúrò níbẹ̀ pẹlu ọpọlọpọ dúkìá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15

Wo Jẹnẹsisi 15:14 ni o tọ