18 Ní ọjọ́ náà ni OLUWA bá a dá majẹmu, ó sọ pé, “Àwọn ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Ijipti títí dé odò ńlá nì, àní odò Yufurate,
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15
Wo Jẹnẹsisi 15:18 ni o tọ