8 Ṣugbọn Abramu bèèrè pé, “OLUWA Ọlọrun, báwo ni n óo ṣe mọ̀ pé ilẹ̀ náà yóo jẹ́ tèmi?”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15
Wo Jẹnẹsisi 15:8 ni o tọ