Jẹnẹsisi 16:11 BM

11 Wò ó! oyún tí ó wà ninu rẹ, ọkunrin ni o óo fi bí, o óo sọ ọmọ náà ní Iṣimaeli, nítorí OLUWA ti rí gbogbo ìyà tí ń jẹ ọ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 16

Wo Jẹnẹsisi 16:11 ni o tọ