1 Nígbà tí Abramu di ẹni ọdún mọkandinlọgọrun-un, OLUWA farahàn án, ó sọ fún un pé, “Èmi ni Ọlọrun Olodumare, máa gbọ́ tèmi, kí o sì jẹ́ pípé.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17
Wo Jẹnẹsisi 17:1 ni o tọ