Jẹnẹsisi 17:10 BM

10 Majẹmu náà tí ó wà láàrin èmi pẹlu rẹ, ati atọmọdọmọ rẹ, tí ẹ gbọdọ̀ pamọ́ nìyí, gbogbo àwọn ọmọkunrin yín gbọdọ̀ kọlà abẹ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17

Wo Jẹnẹsisi 17:10 ni o tọ