5 Orúkọ rẹ kò ní jẹ́ Abramu mọ́, Abrahamu ni o óo máa jẹ́, nítorí mo ti sọ ọ́ di baba ńlá fún ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17
Wo Jẹnẹsisi 17:5 ni o tọ