Jẹnẹsisi 18:16 BM

16 Nígbà tí àwọn ọkunrin náà kúrò lọ́dọ̀ Abrahamu, wọ́n dojú kọ ọ̀nà Sodomu, Abrahamu bá wọn lọ láti sìn wọ́n dé ọ̀nà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:16 ni o tọ