20 OLUWA bá sọ pé; “Ẹ̀sùn tí àwọn eniyan fi ń kan Sodomu ati Gomora ti pọ̀ jù, ẹ̀ṣẹ̀ wọn burú jáì!
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18
Wo Jẹnẹsisi 18:20 ni o tọ