24 A kì í bàá mọ̀, bí aadọta olódodo bá wà ninu ìlú náà, ṣé o óo pa ìlú náà run, o kò sì ní dá a sí nítorí aadọta olódodo tí ó wà ninu rẹ̀?
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18
Wo Jẹnẹsisi 18:24 ni o tọ