26 OLUWA dáhùn, ó ní, “Bí mo bá rí aadọta olódodo ninu ìlú Sodomu, n óo dá gbogbo ìlú náà sí nítorí tiwọn.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18
Wo Jẹnẹsisi 18:26 ni o tọ