5 Níwọ̀n ìgbà tí ẹ ti yà lọ́dọ̀ èmi iranṣẹ yín, ẹ kúkú jẹ́ kí n tètè tọ́jú oúnjẹ díẹ̀ fún yín láti jẹ, bí ẹ bá tilẹ̀ wá fẹ́ máa lọ nígbà náà, kò burú.”Wọ́n bá dá a lóhùn pé, “Ó dára, lọ ṣe bí o ti wí.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18
Wo Jẹnẹsisi 18:5 ni o tọ