Jẹnẹsisi 19:25 BM

25 ó sì pa ìlú náà run ati gbogbo àfonífojì náà. Ó pa gbogbo àwọn tí wọn ń gbé àwọn ìlú náà run, ati gbogbo ohun tí ó hù lórí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19

Wo Jẹnẹsisi 19:25 ni o tọ