3 Ṣugbọn ó rọ̀ wọ́n gidigidi, wọ́n bá yà sí ilé rẹ̀, ó se àsè fún wọn, ó ṣe àkàrà tí a kò fi ìwúkàrà sí, wọ́n sì jẹun.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19
Wo Jẹnẹsisi 19:3 ni o tọ