5 Wọ́n pe Lọti, wọ́n ní, “Níbo ni àwọn ọkunrin tí wọ́n dé sọ́dọ̀ rẹ ní alẹ́ yìí wà? Kó wọn jáde fún wa, a fẹ́ bá wọn lòpọ̀.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19
Wo Jẹnẹsisi 19:5 ni o tọ