Jẹnẹsisi 2:10 BM

10 Odò kan ṣàn jáde láti inú ọgbà Edẹni tí omi rẹ̀ máa ń mú kí ọgbà náà rin. Lẹ́yìn tí odò yìí ṣàn kọjá ọgbà Edẹni, ó pín sí mẹrin.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2

Wo Jẹnẹsisi 2:10 ni o tọ