12 Wúrà ilẹ̀ náà dára. Turari olówó iyebíye tí wọ́n ń pè ní bedeliumu, ati òkúta olówó iyebíye tí wọ́n ń pè ní onikisi wà níbẹ̀ pẹlu.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2
Wo Jẹnẹsisi 2:12 ni o tọ