Jẹnẹsisi 2:14 BM

14 Orúkọ odò kẹta ni Tigirisi, òun ni ó ṣàn lọ sí apá ìlà oòrùn Asiria. Ẹkẹrin ni odò Yufurate.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2

Wo Jẹnẹsisi 2:14 ni o tọ