21 Nígbà náà OLUWA Ọlọrun kun ọkunrin yìí ní oorun àsùnwọra, nígbà tí ó sùn, Ọlọrun yọ ọ̀kan ninu àwọn egungun ìhà rẹ̀, ó sì fi ẹran dípò rẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2
Wo Jẹnẹsisi 2:21 ni o tọ