Jẹnẹsisi 2:3 BM

3 Ó súre fún ọjọ́ keje yìí, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ọjọ́ náà ni ó sinmi ninu gbogbo iṣẹ́ ìṣẹ̀dá tí ó ti ń ṣe bọ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2

Wo Jẹnẹsisi 2:3 ni o tọ