Jẹnẹsisi 2:7 BM

7 Nígbà náà ni OLUWA Ọlọrun bù ninu erùpẹ̀ ilẹ̀, ó fi mọ eniyan. Ó mí èémí ìyè sí ihò imú rẹ̀, eniyan sì di ẹ̀dá alààyè.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 2

Wo Jẹnẹsisi 2:7 ni o tọ