Jẹnẹsisi 20:10 BM

10 Ó bi Abrahamu pé, “Kí ni èrò rẹ gan-an, tí o fi ṣe ohun tí o ṣe yìí?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20

Wo Jẹnẹsisi 20:10 ni o tọ