Jẹnẹsisi 20:8 BM

8 Abimeleki yára dìde ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, ó pe gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ jọ, ó ro gbogbo nǹkan wọnyi fún wọn, ẹ̀rù sì bà wọ́n gidigidi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20

Wo Jẹnẹsisi 20:8 ni o tọ