Jẹnẹsisi 21:1 BM

1 OLUWA bẹ Sara wò gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, ó sì ṣe fún un gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21

Wo Jẹnẹsisi 21:1 ni o tọ