Jẹnẹsisi 21:22 BM

22 Ní àkókò náà, Abimeleki ati Fikoli, olórí ogun rẹ̀, sọ fún Abrahamu pé, “Ọlọrun wà pẹlu rẹ ninu ohun gbogbo tí ò ń ṣe.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21

Wo Jẹnẹsisi 21:22 ni o tọ