32 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe dá majẹmu ní Beeriṣeba. Abimeleki ati Fikoli, olórí ogun rẹ̀, sì pada lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Filistia.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21
Wo Jẹnẹsisi 21:32 ni o tọ