6 Sara wí pé, “Ọlọ́run ti pa mí lẹ́rìn-ín, gbogbo ẹni tí ó bá gbọ́ ni yóo sì rẹ́rìn-ín.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21
Wo Jẹnẹsisi 21:6 ni o tọ