Jẹnẹsisi 22:11 BM

11 Ṣugbọn angẹli OLUWA pè é láti òkè ọ̀run, ó ní, “Abrahamu! Abrahamu!” Abrahamu dáhùn, ó ní, “Èmi nìyí.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22

Wo Jẹnẹsisi 22:11 ni o tọ