Jẹnẹsisi 22:17 BM

17 n óo bukun ọ lọpọlọpọ, n óo sọ àwọn ọmọ ọmọ rẹ di pupọ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, ati bíi yanrìn etí òkun. Àwọn ọmọ ọmọ rẹ yóo máa ṣẹgun àwọn ọ̀tá wọn ní gbogbo ìgbà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22

Wo Jẹnẹsisi 22:17 ni o tọ