19 Abrahamu bá pada tọ àwọn ọdọmọkunrin rẹ̀ lọ, wọ́n bá jọ gbéra, wọ́n pada lọ sí Beeriṣeba, Abrahamu sì ń gbé ibẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22
Wo Jẹnẹsisi 22:19 ni o tọ