Jẹnẹsisi 22:2 BM

2 Ọlọrun ní, “Mú Isaaki ọmọ rẹ kan ṣoṣo tí o fẹ́ràn, kí o lọ sí ilẹ̀ Moraya, kí o sì fi ọmọ náà rú ẹbọ sísun lórí ọ̀kan ninu àwọn òkè tí n óo júwe fún ọ.”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22

Wo Jẹnẹsisi 22:2 ni o tọ