6 Abrahamu gbé igi ẹbọ sísun náà lé Isaaki, ọmọ rẹ̀ lórí, ó mú ọ̀bẹ ati iná lọ́wọ́. Àwọn mejeeji jọ ń lọ.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22
Wo Jẹnẹsisi 22:6 ni o tọ